summaryrefslogtreecommitdiff
path: root/languages/messages/MessagesYo.php
diff options
context:
space:
mode:
Diffstat (limited to 'languages/messages/MessagesYo.php')
-rw-r--r--languages/messages/MessagesYo.php423
1 files changed, 346 insertions, 77 deletions
diff --git a/languages/messages/MessagesYo.php b/languages/messages/MessagesYo.php
index d4970e37..efa32bb6 100644
--- a/languages/messages/MessagesYo.php
+++ b/languages/messages/MessagesYo.php
@@ -5,6 +5,8 @@
* @file

* @author Demmy
+ * @author Meno25
+ * @author Urhixidur

$messages = array(
@@ -13,6 +15,8 @@ $messages = array(
'tog-justify' => "S'àlàyé gbólóhùn ọ̀rọ̀",
'tog-hideminor' => "Bo àtúnse kékékèé mọ́'lẹ̀ nínú àtúnse tuntun",
'tog-extendwatchlist' => "Fífẹ̀ ìmójútó láti ṣ'àfihàn gbogbo àtúnṣe tó ṣẹ́lẹ̀",
+'tog-editondblclick' => "Ṣ'àtúnṣe àwọn ojúewé ní kíkàn lẹ́mẹjì (JavaScript)",
+'tog-editsection' => 'Jọ̀wọ́ àtúnṣe abala láti inú àwọn ìjápọ̀',
'tog-rememberpassword' => "Sè'rántí ọ̀rọ̀ìpamí mi lórí kọmputa yi",
'tog-watchcreations' => "S'àfikún ojúewé tí mo dá mọ́ ìmójútó mi",
'tog-watchdefault' => "S'àfikún ojúewé tí mo s'àtúnse mọ́ ìmójútó mi",
@@ -25,7 +29,9 @@ $messages = array(
'tog-enotifwatchlistpages' => 'Fi e-mail ránsẹ́ sími tí ojúewé tí mò ún mójútó bá yípadà',
'tog-enotifusertalkpages' => 'Fi e-mail ránsẹ́ sími tí ojúewé ẹnitínse mi bá yípadà',
'tog-enotifminoredits' => 'Fi e-mail ránsẹ́ sími bákannà fún àtúnse kékékèé sí ojúewé',
+'tog-enotifrevealaddr' => "Ṣ'àfihàn ojúọ̀nà e-mail mi nínú àwọn ìránṣẹ́ e-mail",
'tog-shownumberswatching' => "S'àfihàn iye àwọn ẹnitínse tí wọn ún mójútó",
+'tog-forceeditsummary' => 'Kìlọ̀ fún mi tí àkótán àtúnṣe bá jẹ́ òfo',
'tog-watchlisthideown' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe mi nínú ìmójútó',
'tog-watchlisthidebots' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe bot nínú ìmójútó',
'tog-watchlisthideminor' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe kéékèké nínú ìmójútó',
@@ -91,9 +97,12 @@ $messages = array(
# Categories related messages
'pagecategories' => '{{PLURAL:$1|Ẹ̀ka|Àwọn ẹ̀ka}}',
'category_header' => 'Àwọn ojúewé nínú ẹ̀ka "$1"',
+'subcategories' => 'Àwọn abẹẹ̀ka',
+'category-media-header' => 'Amóunmáwòrán nínú ẹ̀ka "$1"',
'category-empty' => "''Lọ́wọ́lọ́wọ́ ẹ̀ka yìí kò ní ojúewé tàbí amóhùnmáwòrán kankan.''",
'hidden-categories' => '{{PLURAL:$1|Ẹ̀ka àbòmọ́lẹ̀|Áwọn ẹ̀ka àbòmọ́lẹ̀}}',
'hidden-category-category' => 'Àwọn ẹ̀ka àbòmọ́lẹ̀', # Name of the category where hidden categories will be listed
+'category-article-count' => '{{PLURAL:$2|Ẹ̀ka yìí ní ojúewé kan péré.|{{PLURAL:$1|Ojúewé kan yìí nìkan|Àwọn ojúewé $1 yìí}} lówà nínú èka yìí, nínú àpapọ̀ $2.}}',
'listingcontinuesabbrev' => 'tẹ̀síwájú',
'about' => 'Nípa',
@@ -111,6 +120,9 @@ $messages = array(
'navigation' => 'Atọ́ka',
'and' => 'àti',
+# Metadata in edit box
+'metadata_help' => 'Metadata:',

'errorpagetitle' => 'Àsìse',
'returnto' => 'Padà sí $1.',
'tagline' => "Lát'ọwọ́ {{SITENAME}}",
@@ -133,6 +145,7 @@ $messages = array(
'delete' => 'Paarẹ́',
'deletethispage' => 'Pa ojúewé yi rẹ́',
'protect' => 'Dábòbò',
+'protect_change' => 'yípadà',
'protectthispage' => 'Dá àbò bo ojúewé yìí',
'unprotect' => 'Mú àbò kúrò',
'unprotectthispage' => 'Mú àbò kúrò lórí ojúewé yìí',
@@ -159,6 +172,7 @@ $messages = array(
'lastmodifiedat' => 'Ọjọ́ tí a ṣe àtunṣe ojúewé yi gbẹ̀yìn ni $2, $1.', # $1 date, $2 time
'viewcount' => 'A ti wo ojúewé yi ni {{PLURAL:$1|ẹ̀kan péré|iye ìgbà $1}}.',
'protectedpage' => 'Ojúewé aláàbò',
+'jumpto' => 'Fò sí:',
'jumptonavigation' => 'atọ́ka',
'jumptosearch' => "
ṣ'àwáàrí",
@@ -166,6 +180,8 @@ $messages = array(
# All link text and link target definitions of links into project namespace that get used by other message strings, with the exception of user group pages (see grouppage) and the disambiguation template definition (see disambiguations).
'aboutsite' => 'Nípa {{SITENAME}}',
'aboutpage' => 'Project:Nípa',
+'bugreports' => 'Ìjábọ̀ àsìṣe',
+'bugreportspage' => 'Project:Ìjábọ̀ àsìṣe',
'copyright' => 'Gbogbo ohun inú ibí yi wà lábẹ́ $1.',
'copyrightpagename' => '{{SITENAME}} ẹ̀tọ́àwòkọ',
'copyrightpage' => '{{ns:project}}:Ẹ̀tọ́àwòko',
@@ -175,14 +191,18 @@ $messages = array(
'disclaimerpage' => 'Project:Ìkìlọ̀ gbogbo',
'edithelp' => "Ìrànlọ́wọ́ láti s'àtúnṣe",
'edithelppage' => 'Help:Àtúnṣe',
+'helppage' => 'Help:Àwon ohunnú',
'mainpage' => 'Ojúewé Àkọ́kọ́',
'mainpage-description' => 'Ojúewé Àkọ́kọ́',
'portal' => 'Èbúté àwùjọ',
'portal-url' => 'Project:Èbúté Àwùjọ',
+'privacy' => 'Ètò àbò',
+'privacypage' => 'Project:Ètò àbò',
'badaccess-group0' => "A kò gbàyín l'áyè l'áti ṣe ohun tí ẹ bèrè fún.",
'ok' => 'OK',
+'retrievedfrom' => 'Kójáde láti "$1"',
'youhavenewmessages' => 'Ẹ ní $1 ($2).',
'newmessageslink' => 'ìfọ̀rọ̀ránsẹ́ tuntun',
'newmessagesdifflink' => 'àtúnṣe ìgbẹ̀yìn',
@@ -191,13 +211,17 @@ $messages = array(
'editold' => "s'àtúnṣe",
'viewsourceold' => 'wo àmìọ̀rọ̀',
'editsectionhint' => 'Abala àtúnṣe: $1',
+'toc' => 'Ohunnú',
'showtoc' => 'fihàn',
'hidetoc' => 'bòmọ́lẹ̀',
'thisisdeleted' => 'Wo tàbí múpadà $1?',
'viewdeleted' => 'Wo $1?',
'restorelink' => '{{PLURAL:$1|àtúnṣe tóparẹ́ kan|àtúnṣe tóparẹ́ $1}}',
+'feedlinks' => 'Feed:',
'site-rss-feed' => '$1 RSS Feed',
'site-atom-feed' => '$1 Atom Feed',
+'page-rss-feed' => '"$1" RSS Feed',
+'page-atom-feed' => '"$1" Atom Feed',
# Short words for each namespace, by default used in the namespace tab in monobook
'nstab-main' => 'Àyọkà',
@@ -221,6 +245,7 @@ $messages = array(
# General errors
'error' => 'Àsìṣe',
+'missingarticle-rev' => '(àtúnyẹ̀wò#: $1)',
'missingarticle-diff' => '(Ìyàtọ̀: $1, $2)',
'filecopyerror' => 'Àwòkọ faili "$1" sí "$2" kò ṣe é ṣe.',
'filerenameerror' => 'Àtúnsọlórúkọ faili "$1" sí "$2" kò ṣe é ṣe.',
@@ -228,10 +253,13 @@ $messages = array(
'directorycreateerror' => 'Ìwé-ìjúwe "$1" kò ṣe é ṣe.',
'filenotfound' => 'Kò le é ṣe àwáàrí faili "$1".',
'badtitle' => 'Àkọ́lé burúkú',
+'badtitletext' => 'Àkọlé ojúewé tí ẹ bèrè fún kò ní ìbámu, jẹ́ òfo, tàbí áṣìṣe wà nínú ìjápọ̀ àkọlé láàrin èdè tàbí láàrin wiki.
+Ó ṣe é ṣe kó jẹ́pé ó ní ìkan tàbí ọ̀pọ̀ àmi lẹ́tà tí kò ṣe é lò nínú àkọlé.',
'viewsource' => 'Àfihàn ọ̀rọ̀àmì',
'viewsourcefor' => 'fún $1',
'protectedpagetext' => 'A ti se àtìpa ojúewé yi. Ẹ kò le se àtúnṣe.',
'viewsourcetext' => 'Ẹ lè wo ati ẹ lè se àwòkọ ọ̀rọ̀àmì ojúewé yi:',
+'namespaceprotected' => "A kò gbàyín ní ààyè láti ṣ'àtúnṣe àwọn ojúewé tó wà nínú orúkọàyè '''$1'''.",
'ns-specialprotected' => 'Àtúnṣe kò ṣe é ṣe sí àwọn ojúewé pàtàkì.',
'titleprotected' => "This title has been protected from creation by [[User:$1|$1]]. The reason given is ''$2''.",
@@ -249,9 +277,11 @@ A ti fi orúkọ yín s'ílẹ̀. Ẹ mọ́ gbàgbé l'áti s'àtúnṣe àwọ
'yourpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́:',
'yourpasswordagain' => 'Tẹkíkọ ọ̀rọ̀ìpamọ́ lẹ́ẹ̀kansí:',
'remembermypassword' => "Sè'rántí ọ̀rọ̀ìpamí mi lórí kọmputa yi (cookies)",
+'yourdomainname' => 'Domain yín:',
'loginproblem' => 'Ẹ ní ìṣòro láti wọlé.
Ẹ gbìyànjú lẹ́kan sí!',
'login' => 'Ìwọlé',
'nav-login-createaccount' => 'Ìwọlé / Ìforúkọ sílẹ̀',
+'loginprompt' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ jọ̀wọ́ cookies láti wọlé sí {{SITENAME}}.',
'userlogin' => 'Ìwọlé / ìforúkọ sílẹ̀',
'logout' => 'Ìbọ́sóde',
'userlogout' => 'Ìbọ́sóde',
@@ -272,20 +302,31 @@ A ti fi orúkọ yín s'ílẹ̀. Ẹ mọ́ gbàgbé l'áti s'àtúnṣe àwọ
'badsiglength' => 'Ìtọwọ́bọ̀ yín ti gùnjù.
Kò gbodọ̀ ju {{PLURAL:$1|àmìlẹ́tà|àwọn àmìlẹ́tà}} $1 lọ.',
'email' => 'E-mail',
+'prefs-help-realname' => 'Orúkọ gangan kò pọndandan.
+Tí ẹ bá fisílẹ̀ a ó lòó láti tóka iṣẹ́ yín fún yín.',
'loginerror' => 'Àsìṣe ìwọlé',
'prefs-help-email-required' => 'E-mail ṣe dandan.',
'noname' => 'Ẹ kò tọ́kasí orúkọ oníṣe tó ní ìbámu.',
'loginsuccesstitle' => 'Ìwọlé ti yọrí sí rere',
'loginsuccess' => "'''Ẹ ti wọlé sínú {{SITENAME}} gẹ́gẹ́ bi \"\$1\".'''",
'nosuchuser' => 'Kò sí oníṣe kankan pẹ̀lú orúkọ "$1".
-Ẹ yẹ lẹ́tà yín wò, tàbí [[Special:Userlogin/signup|kí ẹ s\'èdá àpamọ́ tuntun]].',
+Ẹ yẹ lẹ́tà yín wò, tàbí [[Special:UserLogin/signup|kí ẹ s\'èdá àpamọ́ tuntun]].',
+'nosuchusershort' => "Kò sí oníṣe t'ón jẹ́ <nowiki>$1</nowiki>.
+Ẹ wo spelling yín.",
'nouserspecified' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ tọ́kasí orúkọ oníṣe kan.',
'wrongpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ tí ẹ kìbọ́ kòtọ́.
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kansí.',
+'wrongpasswordempty' => 'Ọ̀ròìpamọ́ jẹ́ òfo.
+Ẹ gbìyànjú lẹ́ ẹ̀kan síi.',
'passwordtooshort' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ yín jẹ́ aláìtọ́ tàbí ó kúrú ju bóṣe yẹ lọ.
Kò gbọ́dọ̀ dín ju {{PLURAL:$1|àmìlẹ́tà kan|àmìlẹ́tà $1}} lọ, kí ó sì yàtọ̀ sí oríkọoníṣe yín.',
'mailmypassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ tuntun sí e-mail',
+'passwordremindertitle' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ tuntun fún ìgbà díẹ̀ fún {{SITENAME}}',
'noemail' => 'Kò sí àkọsílẹ̀ ojúọ̀nà e-mail fún oníṣe "$1".',
+'passwordsent' => 'A ti fi ọ̀rọ̀ìpamọ́ tuntun ránṣẹ́ sí ojúọ̀nà e-mail tí a fisílẹ̀ fún "$1".
+Ẹ jọ̀wọ́ ẹ padà wọlé tí ẹ bá ti gbàá.',
+'eauthentsent' => 'A ti fi e-mail ìmúdájú ránṣẹ́ sí ojúọ̀nà e-mail tí ẹ fi sílẹ̀.
+Kí á tó fi e-mail mìíràn ránṣẹ́ sí àpamọ́ yìí, ẹ gbọ́dọ̀ tẹ̀lé àwọn ìlànà inú e-mail ọ̀ún, láti fidájú pé àpamọ́ ọ̀ún jẹ́ ti yín lóòótọ́.',
'emailconfirmlink' => 'Ẹ ṣe ìmúdájú ojúọ̀nà e-mail yín',
'accountcreated' => 'Ẹ ti fi orúkọ sílẹ̀',
'accountcreatedtext' => "A ti ṣ'èdá àpamọ́ oniṣe fún $1.",
@@ -298,11 +339,28 @@ Kò gbọ́dọ̀ dín ju {{PLURAL:$1|àmìlẹ́tà kan|àmìlẹ́tà $1}} l
'resetpass_success' => 'Ìyípadà ọ̀rọ̀ìpamọ́ yín ti já sí rere! Ẹ̀ ún wọlé lọ́wọ́...',
# Edit page toolbar
-'link_sample' => 'Àkọlé ìjápọ̀',
-'media_tip' => 'Ìjápọ̀ faili',
+'bold_sample' => 'Ìkọ kedere',
+'bold_tip' => 'Ìkọ kedere',
+'italic_sample' => 'Ìkọ italiki',
+'italic_tip' => 'Ìkọ italiki',
+'link_sample' => 'Àkọlé ìjápọ̀',
+'link_tip' => "Ìjápọ̀ s'ínú",
+'extlink_sample' => 'http://www.example.com àkọlé ìjápọ̀',
+'extlink_tip' => "Ìjápọ̀ s'íta (ẹ mọ́ gbàgbé http:// prefix)",
+'headline_sample' => 'Ìkọ àkọlé',
+'headline_tip' => 'Àkọlé onípele 2',
+'math_sample' => "Ẹ fi àgbékalẹ̀ s'íhín",
+'math_tip' => 'Àgbékalẹ̀ ìsirò (LaTeX)',
+'nowiki_sample' => "Ẹ fi ìkọ tí kò létò s'íhín",
+'nowiki_tip' => 'Ẹ fojú fo étò wiki',
+'image_tip' => 'Faili tí a kìbọ̀',
+'media_tip' => 'Ìjápọ̀ faili',
+'sig_tip' => 'Ìtọwọ́bọ̀ yín pẹ̀lú àmì-àsìkò',
+'hr_tip' => 'Ìlà gbọlọjọ (ẹ lọ̀ọ́ pẹ̀lú àkíyèsì)',
# Edit pages
'summary' => 'Àkótán',
+'subject' => 'Orí ọ̀rọ̀/àkọlé',
'minoredit' => 'Àtúnṣe kékeré nìyí',
'watchthis' => "M'ójútó ojúewé yìí",
'savearticle' => 'Ẹ fi pamọ́',
@@ -311,7 +369,21 @@ Kò gbọ́dọ̀ dín ju {{PLURAL:$1|àmìlẹ́tà kan|àmìlẹ́tà $1}} l
'showdiff' => 'Àfihàn àwọn àyípadà',
'anoneditwarning' => "'''Ìkìlọ̀:''' Ẹ ò tíì wọlé.
Á ṣe àkọsílẹ̀ ojúọ̀nà IP yín ninu ìwé àtúnṣe ojúewé yìí.",
+'summary-preview' => 'Àyẹ̀wò àkótán',
'blockedtitle' => 'Ìdènà sí oníṣe',
+'blockedtext' => "'''A ti dínà orúkọ oníṣe tàbí ojúọ̀nà IP yín.'''

+$1 ni ó ṣe ìdínà.
+Ìdí tó fun ni ''$2''.

+* Ìbẹ̀rẹ̀ ìdínà: $8
+* Ìparí ìdínà: $6
+* Ẹni tí a fẹ́ dínà: $7

+Ẹ ṣ'èránṣẹ́ sí $1 tàbí [[{{MediaWiki:Grouppage-sysop}}|alámùójútó]] mìíràn láti fọ̀rọ̀wérọ̀ lórí ìdínà ọ̀ún.
+Ẹ kò le è 'ránṣẹ́ sí oníṣe yìí pẹ̀lú e-mail' àyàfi tí ojúọ̀nà e-mail tó dájú wà ní [[Special:Preferences|àwọn ìfẹ́ràn àpamọ́]] yín tí wọn kò sì ti dínà yín láti lò ó.
+Ojúọ̀nà IP yín lọ́wọ́lọ́wọ́ ni $3, bẹ́ ẹ̀ sì ni ID fún ìdínà yín ni #$5.
+Ẹ jọ̀wọ́ ẹ fi gbogbo ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ òkè yìí kún ìbérè tí ẹ bá ṣe.",
'whitelistedittitle' => "Ìwọlé ṣe dandan láti ṣ'àtúnṣe",
'whitelistedittext' => "Ẹ gbọ́dọ̀ $1 láti ṣ'àtúnṣe àwọn ojúewé.",
'confirmedittitle' => "Ìmúdájú E-mail ṣe dandan láti ṣ'àtúnṣe",
@@ -325,18 +397,29 @@ Kò gbọ́dọ̀ dín ju {{PLURAL:$1|àmìlẹ́tà kan|àmìlẹ́tà $1}} l
'newarticletext' => "Ẹ ti tẹ̀lé ìjápọ̀ mọ́ ojúewé tí kò sí.
Láti dá ojúewé yí ẹ bẹ̀rẹ̀ síní tẹ́kọ sí inú àpótí ìsàlẹ̀ yí (ẹ wo [[{{MediaWiki:Helppage}}|ojúewé ìrànlọ́wọ́ ]] fun ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ).
T'óbá sepé àsìse ló gbé yin dé bi, ẹ kọn bọ́tìnì ìpadàsẹ́yìn.",
+'noarticletext' => "Lọ́wọ́lọ́wọ́ kò sí ìkọ nínú ojúewé yìí, ẹ le [[Special:Search/{{PAGENAME}}|s'àwáarí fún àkọlé ojúewé yìí]] nínú àwọn ojúewé mìíràn tàbí [{{fullurl:{{FULLPAGENAME}}|action=edit}} kí ẹ ṣ'àtúnṣe ojúewé òún].",
'note' => 'Àkíyèsí:',
+'previewnote' => 'Àyẹ̀wò kan ni èyí;
+àwọn àtúnṣe kò tíì pamọ́!',
'session_fail_preview' => 'Àforíjìn! A kò le gbésẹ̀ àtúnṣe yín nítorí ìpòfo data ìsinsìyí.
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ gbìyànjú lẹ́ẹ̀kan si.
Tí kò bá sì tún ṣiṣẹ́, ẹ gbìyànjú láti [[Special:UserLogout|bọ̀sòde]] kí ẹ sì padá wọlé.',
'editing' => 'Àtúnṣe sí $1',
+'editingsection' => 'Àtúnṣe sí $1 (abala)',
'yourdiff' => 'Àwọn ìyàtọ̀',
'copyrightwarning' => 'Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kíyèsi wípé gbogbo àwọn àfikún sí {{SITENAME}} jẹ́ bẹ̀ lábẹ́ $2 (Ẹ wo $1 fún ẹkunrẹrẹ).
Tí ẹ kò bá fẹ́ kí ìkọọ́lẹ̀ yín ó jẹ́ títúnṣe tàbí kì ó jẹ́ pípìn kiri lọ́ná tí kò wù yín, ẹ mọ́ mù wá síbí.

Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín, tàbí ẹ wòókọ láti agbègbè ìgboro tàbí irú ìtìlẹ́yín ọ̀fẹ́ bíi bẹ́ẹ̀.
Ẹ MỌ́ MÚ IṢẸ́ TÓ NÍ Ẹ̀TỌ́ÀWÒKỌ SÍLẸ̀ LÁÌ GBÀṢẸ!',
+'longpagewarning' => "ÌKILỌ̀: Ojúewé yìí jẹ́ $1 kilobytes ní gúngùn;
+àwọn browsers míràn le è ní ṣòro láti ṣ'àtúnṣe àwọn ojúewé tó tó tàbí tògùnju 32 kb lọ.
+Ẹ jọ̀wọ́ ẹ rò ó wò bóyá ẹ lè fọ́ ojúewé ọ̀ún sí abala kéékèké.",
+'templatesused' => 'Àwọn àdàkọ tí a lò lórí ojúewé yìí:',
+'templatesusedpreview' => 'Àwọn àdàkọ tí a lò nìnú àgbéyẹ́wò yìí:',
'template-protected' => '(aláàbò)',
'template-semiprotected' => '(aláàbò díẹ̀)',
+'nocreatetext' => "{{SITENAME}} ti pààlà ààyè láti ṣ'èdá ojúewé tuntun.
+Ẹ le padà sẹ́yìn kí ẹ ṣ'àtúnṣe ojúewé tó wà, tàbí [[Special:UserLogin|kí ẹ wọlé tàbí kí ẹ ṣ'èdá àpamọ́]].",
'recreate-deleted-warn' => "'''Ìkìlọ̀: Ẹ̀ ún ṣ'èdá ojúewé tí a ti parẹ́ tẹ́lẹ̀.'''
Ẹ gbọ́dọ̀ gberò bóyá ó bójúmu láti tẹ̀síwájú pẹ̀lú àtúnṣe ojúewé yìí.
@@ -346,6 +429,7 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'cantcreateaccounttitle' => 'Ìforúkọsílẹ̀ kò se é se',
# History pages
+'viewpagelogs' => 'Ẹ wo àkọsílẹ̀ fún ojúewé yìí',
'currentrev' => 'Àtúnyẹ̀wò ìsinsìnyí',
'revisionasof' => 'Àtúnyẹ̀wò ní $1',
'revision-info' => "Àtúnyẹ̀wò ní $1 l'átọwọ́ $2",
@@ -358,6 +442,8 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'page_first' => 'àkọ́kọ́',
'page_last' => 'tógbẹ̀yìn',
'deletedrev' => '[tiparẹ́]',
+'histfirst' => 'Pípẹ́jùlọ',
+'histlast' => 'Tuntunjùlọ',
'historyempty' => '(òfo)',
# Revision feed
@@ -373,7 +459,11 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'revdelete-uname' => 'orúkọ oníṣe',
# Diffs
-'editundo' => 'dápadà',
+'history-title' => 'Ìtàn àtúnyẹ̀wò fún "$1"',
+'difference' => '(Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ́wò)',
+'lineno' => 'Ìlà $1:',
+'compareselectedversions' => 'Ìfiwéra àwọn àtúnṣe ìṣàyàn',
+'editundo' => 'dápadà',
# Search results
'searchresults' => 'Àwọn èsì àwáàrí',
@@ -399,7 +489,7 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'mypreferences' => 'Àwọn ìfẹ́ràn mi',
'prefs-edits' => 'Iye àwọn àtúnṣe:',
'prefsnologin' => 'Ẹ kò tíì wọlé',
-'prefsnologintext' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ [{{fullurl:Special:Userlogin|returnto=$1}} wọlé] láti to àwọn ìfẹ́ràn oníṣe.',
+'prefsnologintext' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ [{{fullurl:Special:UserLogin|returnto=$1}} wọlé] láti to àwọn ìfẹ́ràn oníṣe.',
'changepassword' => 'Ìyípadà ọ̀rọ̀ìpamọ́',
'skin' => 'Skin (Àwọ̀)',
'dateformat' => 'Ìṣájúètò ọjọ́',
@@ -413,6 +503,7 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'resetprefs' => 'Palẹ̀mọ́ àwọn àtúnṣe tí kò sì ní ìpamọ́',
'oldpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ titẹ́lẹ̀:',
'newpassword' => 'Ọ̀rọ̀ìpamọ́ tuntun:',
+'retypenew' => 'Àtúntẹ̀ ọ̀rọ̀ìpamọ́ tuntun:',
'searchresultshead' => 'Àwáàrí',
'savedprefs' => 'Àwọn ìfẹ́ràn yín ti wà nípamọ́.',
'prefs-searchoptions' => 'Àwọn ìyàn àwáàrí',
@@ -429,29 +520,40 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'grouppage-bot' => '{{ns:project}}:Àwọn Bot',
'grouppage-sysop' => '{{ns:project}}:Àwọn alámùójútó',
+# User rights log
+'rightslog' => 'Àwọn ẹ̀tọ́ oníṣe',

# Recent changes
-'recentchanges' => 'Àwọn àtúnṣe tuntun',
-'rcnote' => "Lábẹ́ yìí ni {{PLURAL:$1|àtúnṣe '''kan'''|àwọn àtúnṣe '''$1'''}} tó kẹ̀yìn ní ọjọ́ '''$2''' sẹ́yìn, ní ago $5, ọjọ́ $4.",
-'rcshowhideminor' => '$1 àwọn àtúnṣe kékéèké',
-'rcshowhidebots' => '$1 àwọn bot',
-'rcshowhideliu' => '$1 àwọn oníṣe tótiwọlé',
-'rcshowhideanons' => '$1 àwọn oníṣe aláìlórúkọ',
-'rcshowhidemine' => '$1 àwọn àtúnṣe mi',
-'rclinks' => "Ṣ'àfihàn àtúnṣe $1 tó kẹ̀yìn ní ọjọ́ $2 sẹ́yìn
$3",
-'diff' => 'ìyàtọ̀',
-'hist' => 'ìtàn',
-'hide' => 'Ìbòmọ́lẹ̀',
-'show' => 'Àfihàn',
-'minoreditletter' => 'k',
-'newpageletter' => 'T',
-'boteditletter' => 'b',
-'rc_categories_any' => 'Èyíkéyìí',
-'newsectionsummary' => '/* $1 */ abala tuntun',
+'nchanges' => '{{PLURAL:$1|àtúnṣe|àwọn àtúnṣe}} $1',
+'recentchanges' => 'Àwọn àtúnṣe tuntun',
+'recentchanges-feed-description' => 'Ẹ tẹ̀ lé àwọn àtúnṣe àìpẹ́ ọjọ́ sí wiki nínú àkótán feed yìí.',
+'rcnote' => "Lábẹ́ yìí ni {{PLURAL:$1|àtúnṣe '''kan'''|àwọn àtúnṣe '''$1'''}} tó kẹ̀yìn ní ọjọ́ '''$2''' sẹ́yìn, ní ago $5, ọjọ́ $4.",
+'rcnotefrom' => "Àwọn àtúnṣe láti ''''$2''' (títí dé '''$1''' hàn) lábẹ́.",
+'rclistfrom' => 'Àfihàn àwọn àtúnṣe tuntun nípa bíbẹ̀rẹ̀ láti $1',
+'rcshowhideminor' => '$1 àwọn àtúnṣe kékéèké',
+'rcshowhidebots' => '$1 àwọn bot',
+'rcshowhideliu' => '$1 àwọn oníṣe tótiwọlé',
+'rcshowhideanons' => '$1 àwọn oníṣe aláìlórúkọ',
+'rcshowhidepatr' => '$1 àwọn àtúnṣe ọlùṣọ́',
+'rcshowhidemine' => '$1 àwọn àtúnṣe mi',
+'rclinks' => "Ṣ'àfihàn àtúnṣe $1 tó kẹ̀yìn ní ọjọ́ $2 sẹ́yìn
$3",
+'diff' => 'ìyàtọ̀',
+'hist' => 'ìtàn',
+'hide' => 'Ìbòmọ́lẹ̀',
+'show' => 'Àfihàn',
+'minoreditletter' => 'k',
+'newpageletter' => 'T',
+'boteditletter' => 'b',
+'rc_categories_any' => 'Èyíkéyìí',
+'newsectionsummary' => '/* $1 */ abala tuntun',
# Recent changes linked
-'recentchangeslinked' => 'Àtúnṣe tó báramu',
-'recentchangeslinked-title' => 'Àtúnṣe tó báramu mọ́ "$1"',
-'recentchangeslinked-page' => 'Orúkọ ojúewé:',
+'recentchangeslinked' => 'Àtúnṣe tó báramu',
+'recentchangeslinked-title' => 'Àtúnṣe tó báramu mọ́ "$1"',
+'recentchangeslinked-noresult' => 'Kò sí ìyàtọ̀ nínú àwọn ojúewé ìjápọ̀ láàrin ìgbà tí ẹ sọ.',
+'recentchangeslinked-summary' => "Àkójọ àwọn àtúnṣe tí a sẹ̀sẹ̀ ṣe sí àwọn ojúewé tó jápọ̀ wá láti ojúewé pàtó kan (tàbí sí ìkan nìnú ẹ̀ka pàtó kan).
+Àwọn ojúewé inú [[Special:Watchlist|ìmójútó yín]] jẹ́ '''kedere'''.",
+'recentchangeslinked-page' => 'Orúkọ ojúewé:',
# Upload
'upload' => 'Ìrùsókè faili',
@@ -460,6 +562,7 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'uploadnologin' => 'Ẹ kò tíì wọlé',
'uploadnologintext' => 'Ẹ gbọ́dọ̀ [[Special:UserLogin|wọlè]] láti rùsókè faili.',
'uploaderror' => 'Àsìse ìrùsókè',
+'uploadlogpage' => 'Àkọsílẹ̀ ìrùsókè',
'filename' => 'Ọrúkọ faili',
'filedesc' => 'Àkótán',
'fileuploadsummary' => 'Àkótán:',
@@ -467,65 +570,117 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'ignorewarning' => 'Fojúfo ìkìlọ̀ sì fi faili pamọ́',
'ignorewarnings' => 'Fojúfo ìkìlọ̀ tó wù kó jẹ́',
'minlength1' => 'Ó kéréjù àwọn orúkọ faili gbọdọ̀ jẹ́ lẹ́tà kan.',
+'uploadedimage' => 'ti ru "[[$1]]" s\'ókè',
# Special:ImageList
+'imagelist' => 'Àkójọ faili',
'imagelist_name' => 'Orúkọ',
'imagelist_user' => 'Oníṣe',
# Image description page
-'filehist' => 'Ìtàn faili',
-'filehist-current' => 'lọ́wọ́',
-'filehist-user' => 'Oníṣe',
-'filehist-comment' => 'Àwísọ',
-'imagelinks' => 'Àwọn ìjápọ̀',
-'linkstoimage' => '{{PLURAL:$1|Ojúewé yí|$1 Àwọn ojúewé yí}} jápọ̀ mọ́ àpò yí:',
+'filehist' => 'Ìtàn faili',
+'filehist-help' => 'Ẹ kan ọjọ́/àsìkò kan láti wo faili òún bó ṣe hàn ní ìgbà na.',
+'filehist-current' => 'lọ́wọ́',
+'filehist-datetime' => 'Ọjọ́/Àsìkò',
+'filehist-user' => 'Oníṣe',
+'filehist-dimensions' => 'Ẹ̀gbẹ̀ẹ̀gbẹ́',
+'filehist-filesize' => 'Ìtóbi faili',
+'filehist-comment' => 'Àwísọ',
+'imagelinks' => 'Àwọn ìjápọ̀',
+'linkstoimage' => '{{PLURAL:$1|Ojúewé yí|$1 Àwọn ojúewé yí}} jápọ̀ mọ́ àpò yí:',
+'nolinkstoimage' => 'Kò sí ojúewé tó jápọ̀ mọ́ faili yìí.',
+'sharedupload' => 'Faili yìí jẹ́ ìrùsókè pínpín pẹ̀lú àwọn iṣẹ́owọ́ mìíràn tí wọ́n n lòó.',
+'noimage' => 'Kò sí faili tí únjẹ́ báun, sùgbọ́n ẹ le ẹ̀ $1.',
+'noimage-linktext' => 'Ìrùsókè ẹyọkan',
+'uploadnewversion-linktext' => 'Ẹ ṣe ìrùsókè àtúnṣe tuntun faili yìí',
# File deletion
'filedelete' => 'Paarẹ́ $1',
'filedelete-submit' => 'Paarẹ́',
# MIME search
-'download' => 'ìrùsílẹ̀',
+'mimesearch' => 'àwáàrí pẹ́lú MIME',
+'download' => 'ìrùsílẹ̀',

+# List redirects
+'listredirects' => 'Àkójọ àwọn àtúnjúwe',

+# Unused templates
+'unusedtemplates' => 'Àdàkọ àìlò',
# Statistics
-'sitestats' => 'Àwọn statistiki {{SITENAME}}',
-'userstats' => 'Àwọn statistiki oníṣe',
+'statistics' => 'Àwọn statistiki',
+'sitestats' => 'Àwọn statistiki {{SITENAME}}',
+'userstats' => 'Àwọn statistiki oníṣe',

+'disambiguations' => 'Àwọn ojúewé ìpínsọ́tọ̀',

+'doubleredirects' => 'Àwọn àtúnjúwe ẹ̀mẹjì',

+'brokenredirects' => 'Àwọn àtúnjúwe tótigé',
'withoutinterwiki' => 'Àwọn ojúewé tí kò ní ìjápọ̀ èdè',
'fewestrevisions' => 'Àwọn ojúewé pẹ̀lú àwọn àtúnyẹ̀wọ̀ tókéréjù',
# Miscellaneous special pages
-'nbytes' => '$1 {{PLURAL:$1|byte|bytes}}',
-'ncategories' => '{{PLURAL:$1|ẹ̀ka|àwọn ẹ̀ka}} $1',
-'nlinks' => '{{PLURAL:$1|ìjápọ̀|àwọn ìjápọ̀}} $1',
-'nrevisions' => '{{PLURAL:$1|àtúnyẹ̀wò|àwọn àtúnyẹ̀wò}} $1',
-'lonelypages' => 'Àwọn ojúewé aláìlóbìí',
-'lonelypagestext' => 'Àwọn ojúewé wọ̀nyí kò ní ìjápọ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn ojúewé míràn nínú {{SITENAME}}.',
-'uncategorizedpages' => 'Àwọn ojúewé aláìlẹ́ka',
-'popularpages' => 'Ojúewé tógbajúmọ̀',
-'wantedcategories' => 'Àwọn ẹ̀ka aláìní',
-'newpages' => 'Àwọn ojúewé tuntun',
-'newpages-username' => 'Orúkọ oníṣe:',
-'move' => 'Yípò',
-'movethispage' => 'Yípò ojúewé yìí',
+'nbytes' => '$1 {{PLURAL:$1|byte|bytes}}',
+'ncategories' => '{{PLURAL:$1|ẹ̀ka|àwọn ẹ̀ka}} $1',
+'nlinks' => '{{PLURAL:$1|ìjápọ̀|àwọn ìjápọ̀}} $1',
+'nmembers' => '{{PLURAL:$1|ará|àwọn ará}} $1',
+'nrevisions' => '{{PLURAL:$1|àtúnyẹ̀wò|àwọn àtúnyẹ̀wò}} $1',
+'lonelypages' => 'Àwọn ojúewé aláìlóbìí',
+'lonelypagestext' => 'Àwọn ojúewé wọ̀nyí kò ní ìjápọ̀ láti ọ̀dọ̀ àwọn ojúewé míràn nínú {{SITENAME}}.',
+'uncategorizedpages' => 'Àwọn ojúewé aláìlẹ́ka',
+'uncategorizedcategories' => 'Àwọn ẹ̀ka aláìlẹ́ka',
+'uncategorizedimages' => 'Àwọn faili aláìlẹ́ka',
+'uncategorizedtemplates' => 'Àwọn àdàkọ aláìlẹ́ka',
+'unusedcategories' => 'Ẹ̀ka àìlò',
+'unusedimages' => 'Faili àìlò',
+'popularpages' => 'Ojúewé tógbajúmọ̀',
+'wantedcategories' => 'Àwọn ẹ̀ka aláìní',
+'wantedpages' => 'Àwọn ojúewé fún wíwá',
+'mostlinked' => 'Àwọn ojúewé tó ní ìjápọ̀ mọ́ jùlọ',
+'mostlinkedcategories' => 'Àwọn ẹ̀ka tó ní ìjápọ̀ mọ́ jùlọ',
+'mostlinkedtemplates' => 'Àwọn àdákọ tó ní ìjápọ̀mọ́ jùlọ',
+'mostcategories' => 'Àwọn ojúewé pẹ̀lú àwọn ẹ̀ka tópọ̀jùlọ',
+'mostimages' => 'Àwọn faili tó ní ìjápọ̀mọ́ jùlọ',
+'mostrevisions' => 'Àwọn ojúewé pẹ̀lu àwọn àtúnyẹ̀wò tópọ̀jùlọ',
+'prefixindex' => 'Ìtọ́ka ìpele',
+'shortpages' => 'Àwọn ojúewé kúkúrú',
+'longpages' => 'Ojúewé gúngùn',
+'deadendpages' => 'Àwọn ojúewé aláìníjàápọ́',
+'protectedpages' => 'Àwọn ojúewé aláàbò',
+'listusers' => 'Àkójọ àwọn oníṣe',
+'newpages' => 'Àwọn ojúewé tuntun',
+'newpages-username' => 'Orúkọ oníṣe:',
+'ancientpages' => 'Àwọn ojúewé tópẹ́jùlọ',
+'move' => 'Yípò',
+'movethispage' => 'Yípò ojúewé yìí',
# Special:Log
'specialloguserlabel' => 'Oníṣe:',
'speciallogtitlelabel' => 'Àkọlé:',
+'log' => 'Àwọn àkọsílẹ̀',
+'all-logs-page' => 'Gbogbo àkọsílẹ̀',
# Special:AllPages
'allpages' => 'Gbogbo ojúewé',
'alphaindexline' => '$1 dé $2',
+'nextpage' => 'Ojúewé tókàn ($1)',
'prevpage' => 'Ojúewé sẹ́yìn ($1)',
+'allpagesfrom' => 'Àgbéhàn ojúewé tó bẹ̀rẹ̀ láti:',
'allarticles' => 'Gbogbo ojúewé',
'allinnamespace' => 'Gbogbo ojúewé ($1 namespace)',
'allnotinnamespace' => 'Gbogbo ojúewé (tí kòsí ní $1 namespace)',
+'allpagessubmit' => 'Ó yá',
+'allpagesprefix' => 'Ìgbéhàn àwọn ojúewé tóbẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú:',
# Special:Categories
'categories' => 'Àwọn ẹ̀ka',
# E-mail user
+'emailuser' => 'Ẹ fi e-mail ránṣẹ́ sí oníṣe yìí',
'emailfrom' => 'Láti:',
'emailto' => 'Sí:',
'emailsubject' => 'Oríọ̀rọ̀:',
@@ -536,14 +691,24 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'watchlist' => 'Ìmójútó mi',
'mywatchlist' => 'Ìmójútó mi',
'watchlistfor' => "(fún '''$1''')",
+'addedwatch' => 'Ti fikún sí ìmójútó',
+'addedwatchtext' => "A ti ṣ'àfikún \"[[:\$1]]\" sí [[Special:Watchlist|ìmójútó]] yín.
+A óò ṣ'àkójọ àwọn àtúnṣe ọjọ́wajú sí ojúewé yìí àti ojúewé ọ̀rọ̀ rẹ̀ sí bẹ̀. Bákanáà ojúewé náà yíò hàn '''kedere''' nìnú [[Special:RecentChanges|àkójọ àwọn àtúnṣe tuntun]] kó le ba à rọrùn láti rí.",
+'removedwatch' => 'Ti mú kúrò nínú ìmójútó',
+'removedwatchtext' => 'A ti yọ ojúewé "[[:$1]]" kúrò nínú [[Special:Watchlist|ìmójútó yín]].',
'watch' => "M'ójútó",
'watchthispage' => "M'ójútó ojúewé yi",
'unwatch' => "Já'wọ́ ìmójútó",
'unwatchthispage' => "Já'wọ́ ìmójútó ojúewé yi",
+'watchlist-details' => '{{PLURAL:$1|Ojúewé $1|Àwọn ojúewé $1}} ló wà nínú ìmójútó yín, tí a kò bá ka àwọn ojúewé ọ̀rọ̀.',
+'wlshowlast' => 'Áfihàn wákàtí $1 sẹ́yìn ọjọ́ $2 sẹ́yìn $3',
+'watchlist-hide-bots' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe bot',
+'watchlist-hide-own' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe mi',
'watchlist-hide-minor' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ àwọn àtúnṣe kékéèké',
# Displayed when you click the "watch" button and it is in the process of watching
-'watching' => 'Ún mójútó...',
+'watching' => 'Ún mójútó...',
+'unwatching' => 'Jíjáwọ́ ìmójútó...',
'enotif_impersonal_salutation' => 'Oníṣe {{SITENAME}}',
'changed' => 'tiyípadà',
@@ -551,10 +716,41 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'enotif_subject' => '$PAGEEDITOR $CHANGEDORCREATED ojúewé $PAGETITLE lórí {{SITENAME}}',
# Delete/protect/revert
-'deletedarticle' => 'A ti pa "[[$1]]" rẹ́',
+'deletepage' => 'Pa ojúewé rẹ́',
+'historywarning' => 'Ìkìlọ̀: Ojúewé tí ẹ fẹ́ parẹ́ ní ìtàn:',
+'actioncomplete' => 'Ìmúṣe ti parí',
+'deletedtext' => 'A ti pa "<nowiki>$1</nowiki>" rẹ́.
+Ẹ wo $2 fún àkọọ́lẹ̀ àwọn ìparẹ́ àìpẹ́.',
+'deletedarticle' => 'A ti pa "[[$1]]" rẹ́',
+'dellogpage' => 'Àkọsílẹ̀ ìparẹ́',
+'deletecomment' => 'Ìdí fún ìparẹ́:',
+'deleteotherreason' => 'Àwọn ìdí mìíràn:',
+'deletereasonotherlist' => 'Ìdí mìíràn',
+'rollbacklink' => 'yísẹ́yìn',
+'protectlogpage' => 'Àkọsílẹ̀ àbò',
+'protectcomment' => 'Àríwí:',
+'protectexpiry' => 'Ìparí:',
+'protect_expiry_invalid' => 'Àkókò ìparí kò ní ìbámu.',
+'protect_expiry_old' => 'Ìgbà tó ti kọjá ni ìparí.',
+'protect-unchain' => 'Ṣíṣí ìyọ̀nda láti yípò',
+'protect-text' => "Ẹ lè wo, bẹ́ ẹ̀ sìni ẹ lè ṣ'àtúnṣe ibi àbò níbí fún ojúewé <nowiki>$1</nowiki>.",
+'protect-locked-access' => "Àpamọ́ yín kò ní àyè láti ṣ'àtúnṣe àwọn ibi àbò.
+Bí a ṣe to ojúewé $1 nì yí:",
+'protect-default' => '(ìbáwá)',
+'protect-fallback' => 'Ìyọ̀nda "$1" pọn dandan',
+'protect-level-autoconfirmed' => 'Dínà àwọn oníṣe tíkòforúkọ sílẹ́',
+'protect-level-sysop' => 'Alámùójútó nìkan',
+'protect-expiring' => 'parí ní $1 (UTC)',
+'protect-cantedit' => "Ẹ kò le è ṣe àyípadà ibi àbò ojúewé yìí, nítorípé a kò yọ̀nda yín láti ṣ'àtúnṣe rẹ̀.",
+'restriction-type' => 'Ìyọ̀nda:',
+'restriction-level' => 'Ibi ìpàlà:',

+# Undelete
+'undeletebtn' => 'Múpadà',
# Namespace form on various pages
'namespace' => 'Orúkọàyè:',
+'invert' => 'Ìdorípo àsàyàn',
'blanknamespace' => '(Gbangba)',
# Contributions
@@ -565,18 +761,31 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'month' => 'Láti osù (àti sẹ́yìn):',
'year' => 'Láti ọdún (àti sẹ́yìn):',
+'sp-contributions-newbies-sub' => 'Fún àwọn àpamọ́ tuntun',
+'sp-contributions-blocklog' => 'Àkọsílẹ̀ ìdínà',

# What links here
'whatlinkshere' => 'Ìjápọ̀ mọ́ ojúewé yí',
'whatlinkshere-title' => 'Àwọn ojúewé tó jápọ̀ mọ́ "$1"',
'whatlinkshere-page' => 'Ojúewé:',
+'linkshere' => "Àwọn ojúewé wọ̀nyí jápọ̀ mọ́ '''[[:$1]]''':",
+'nolinkshere' => "Kò sí ojúewé tó jápọ̀ mọ́ '''[[:$1]]'''.",
'isredirect' => 'àtúnjúwe ojúewé',
+'istemplate' => 'ìkómọ́ra',
+'whatlinkshere-prev' => '{{PLURAL:$1|tẹ́lẹ̀|tẹ́lẹ̀ $1}}',
+'whatlinkshere-next' => '{{PLURAL:$1|tókàn|tókàn $1}}',
'whatlinkshere-links' => '← àwọn ìjápọ̀',
# Block/unblock
-'ipbsubmit' => 'Dènà oníṣe yìí',
-'ipboptions' => 'wákàtí 2:2 hours,ọjọ́ 1:1 day,ọjọ́ 3:3 days,ọ̀ṣẹ̀ 1:1 week,ọ̀ṣẹ̀ 2:2 weeks,osù 1:1 month,osù 3:3 months,osù 6:6 months,ọdún 1:1 year,láìlópin:infinite', # display1:time1,display2:time2,...
-'blocklink' => 'dínà',
-'contribslink' => 'àfikún',
+'blockip' => 'Dínà oníṣe',
+'ipbsubmit' => 'Dènà oníṣe yìí',
+'ipboptions' => '2 wákàtí:2 hours,1 ọjọ́:1 day,3 ọjọ́:3 days,1 ọ̀ṣẹ̀:1 week,2 ọ̀ṣẹ̀:2 weeks,1 osù:1 month,3 osù:3 months,6 osù:6 months,1 ọdún:1 year,láìlópin:infinite', # display1:time1,display2:time2,...
+'ipblocklist' => 'Àwọn ojúọ̀nà IP àti orúkọ ọníṣe tí a dínà',
+'blocklink' => 'dínà',
+'unblocklink' => 'jáwọ́ ìdínà',
+'contribslink' => 'àfikún',
+'blocklogpage' => 'Àkosílẹ̀ ìdínà',
+'blocklogentry' => 'ìdínà [[$1]] yíò parí ní $2 $3',
# Move page
'move-page' => 'Yípò $1',
@@ -587,39 +796,72 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'movepagebtn' => 'Yípò ojúewé',
'pagemovedsub' => 'Ìyípò ti já sí rere',
'movepage-moved' => '\'\'\'"$1" ti yípò sí "$2"\'\'\'', # The two titles are passed in plain text as $3 and $4 to allow additional goodies in the message.
+'articleexists' => 'Ojúewé pẹ̀lú orúkọ un wà tẹ́lẹ̀, tàbí kójẹ́pé orúkọ tí ẹ yàn kò ní ìbámu.
+Ẹ jọ̀wọ́ ẹ yan orúkọ mìíràn.',
'movedto' => 'tiyípò sí',
+'movetalk' => 'Yípò ojúewé ọ̀rọ̀ rẹ̀',
+'1movedto2' => '[[$1]] ti yípò sí [[$2]]',
+'movelogpage' => 'Àkọsílẹ́ ìyípò',
'movereason' => 'Ìdíẹ̀:',
'revertmove' => 'dápadà',
+# Export
+'export' => 'Ìkójáde àwọn ojúewé',

# Namespace 8 related
'allmessages' => 'Àwọn ìránṣẹ́ sistẹmu',
'allmessagesname' => 'Orúkọ',
+# Thumbnails
+'thumbnail-more' => 'Fẹ̀mú tóbi',

+# Import log
+'importlogpage' => 'Ìgbéwọlé àkọọ́lẹ̀',

# Tooltip help for the actions
-'tooltip-pt-userpage' => 'Ojúewé mi',
-'tooltip-pt-mytalk' => 'Ojúewé ọ̀rọ̀ mi',
-'tooltip-pt-preferences' => 'Àwọn ìfẹ́ràn mi',
-'tooltip-pt-watchlist' => 'Àkójọ àwọn ojúewé tí ẹ̀ ún mójútó bóyá wọ́nyí padà',
-'tooltip-pt-mycontris' => 'Àkójọ àwọn àfikún mi',
-'tooltip-pt-login' => 'A gbà yín níyànjú kí ẹwọlé, bótilẹ̀jẹ́pẹ́ kò pọndandan.',
-'tooltip-pt-anonlogin' => 'A gbàyín níyànjú láti wọlé, bótilẹ̀jẹ́pé kò ṣe dandan.',
-'tooltip-pt-logout' => 'Ìbọ́sódé',
-'tooltip-ca-talk' => 'Ìfọ̀rọ̀wérọ̀ nípa ohun inú ojúewé yìí',
-'tooltip-ca-edit' => 'Ẹ le ṣe àtúnṣe sí ojúewé yìí.
+'tooltip-pt-userpage' => 'Ojúewé mi',
+'tooltip-pt-mytalk' => 'Ojúewé ọ̀rọ̀ mi',
+'tooltip-pt-preferences' => 'Àwọn ìfẹ́ràn mi',
+'tooltip-pt-watchlist' => 'Àkójọ àwọn ojúewé tí ẹ̀ ún mójútó bóyá wọ́nyí padà',
+'tooltip-pt-mycontris' => 'Àkójọ àwọn àfikún mi',
+'tooltip-pt-login' => 'A gbà yín níyànjú kí ẹwọlé, bótilẹ̀jẹ́pẹ́ kò pọndandan.',
+'tooltip-pt-anonlogin' => 'A gbàyín níyànjú láti wọlé, bótilẹ̀jẹ́pé kò ṣe dandan.',
+'tooltip-pt-logout' => 'Ìbọ́sódé',
+'tooltip-ca-talk' => 'Ìfọ̀rọ̀wérọ̀ nípa ohun inú ojúewé yìí',
+'tooltip-ca-edit' => 'Ẹ le ṣe àtúnṣe sí ojúewé yìí.
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ lo bọtini àyẹ̀wò kí ẹ tó fipamọ́.',
-'tooltip-ca-protect' => 'Dáàbòbo ojúewé yìí',
-'tooltip-ca-delete' => 'Pa ojúewé yìí rẹ́',
-'tooltip-ca-move' => 'Yípò ojúewé yìí padà',
-'tooltip-ca-watch' => "Ṣ'àfikún ojúewé yìí mọ́ ìmójútó yín",
-'tooltip-search' => "Ṣ'àwáàrí nínú {{SITENAME}}",
-'tooltip-p-logo' => 'Ojúewé Àkọ́kọ́',
-'tooltip-n-mainpage' => 'Ẹ ṣe àbẹ̀wò sí Ojúewé Àkọ́kọ́',
-'tooltip-n-recentchanges' => 'Àkójọ àwọn àtúnṣe tuntun nínú wiki.',
-'tooltip-t-whatlinkshere' => "Àkójọ gbogbo ojúewé wiki tó jápọ̀ s'íbí",
-'tooltip-t-upload' => 'Ìrùsókè àwọn faili',
-'tooltip-t-specialpages' => 'Àkójọ gbogbo àwọn ojúewé pàtàkì',
-'tooltip-ca-nstab-category' => 'Ẹ wo ẹ́ka ojúewé',
-'tooltip-save' => 'Àfipamọ́ àwọn àtúnṣe',
+'tooltip-ca-addsection' => "Ṣ'àríwí sínú ìfọ̀rọ̀wérọ̀.",
+'tooltip-ca-viewsource' => 'Àbò wà lórí ojúewé yìí.
+Ẹ le wo àmìọ̀rọ̀ rẹ̀.',
+'tooltip-ca-protect' => 'Dáàbòbo ojúewé yìí',
+'tooltip-ca-delete' => 'Pa ojúewé yìí rẹ́',
+'tooltip-ca-move' => 'Yípò ojúewé yìí padà',
+'tooltip-ca-watch' => "Ṣ'àfikún ojúewé yìí mọ́ ìmójútó yín",
+'tooltip-ca-unwatch' => 'Ẹ yọ ojúewé yìí kúrò nínú ìmójútó yín',
+'tooltip-search' => "Ṣ'àwáàrí nínú {{SITENAME}}",
+'tooltip-p-logo' => 'Ojúewé Àkọ́kọ́',
+'tooltip-n-mainpage' => 'Ẹ ṣe àbẹ̀wò sí Ojúewé Àkọ́kọ́',
+'tooltip-n-portal' => 'Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ nípa iṣẹ́ọwọ́ yìí',
+'tooltip-n-currentevents' => 'Ìròhìn lọ́wọ́lọ́wọ́',
+'tooltip-n-recentchanges' => 'Àkójọ àwọn àtúnṣe tuntun nínú wiki.',
+'tooltip-n-help' => 'Fún ìrànlọ́wọ́.',
+'tooltip-t-whatlinkshere' => "Àkójọ gbogbo ojúewé wiki tó jápọ̀ s'íbí",
+'tooltip-t-contributions' => 'Ẹ wo àkójọ àwọn àfikún oníṣe yìí',
+'tooltip-t-emailuser' => 'Ẹ fi e-mail ránṣẹ́ sí oníṣe yìí',
+'tooltip-t-upload' => 'Ìrùsókè àwọn faili',
+'tooltip-t-specialpages' => 'Àkójọ gbogbo àwọn ojúewé pàtàkì',
+'tooltip-ca-nstab-user' => 'Ẹ wo ojúewé oníṣe',
+'tooltip-ca-nstab-project' => 'Ẹ wo ojúewé iṣẹ́ọwọ́',
+'tooltip-ca-nstab-image' => 'Ẹ wo ojúewé faili',
+'tooltip-ca-nstab-template' => 'Ẹ wo àdákọ náà',
+'tooltip-ca-nstab-help' => 'Ẹ wo ojúewé ìrànlọ́wọ́',
+'tooltip-ca-nstab-category' => 'Ẹ wo ẹ́ka ojúewé',
+'tooltip-minoredit' => "Ṣ'àmì sí èyí gẹ́gẹ́ bi àtúnṣe kékeré",
+'tooltip-save' => 'Àfipamọ́ àwọn àtúnṣe',
+'tooltip-preview' => 'Àyẹ̀wò àwọn àtúnṣe yín, ẹ jọ̀wọ́ ẹ kọ́kọ́ lo è yí kí ẹ tó fipamọ́!',
+'tooltip-diff' => 'Ìfihàn àwọn àtúnṣe tí ẹ ṣe sí ìkọ yìí.',
+'tooltip-compareselectedversions' => 'Ẹ wo ìyàtò láàrin àwọn àtúnṣe tí a ṣàyàn fún ojúewé yìí.',
+'tooltip-watch' => "Ẹ ṣ'àfikún ojúewé yìí mọ́ ìmójútó yín",
# Attribution
'anonymous' => 'Aláìlórúkọ (àwọn) oníṣe lórí {{SITENAME}}',
@@ -627,8 +869,27 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'lastmodifiedatby' => 'Igba ti a se atunse si ojuewe yi gbeyin ni $2, $1 by $3.', # $1 date, $2 time, $3 user
'siteusers' => '$1 (àwọn) oníṣe lórí {{SITENAME}}',
+# Browsing diffs
+'previousdiff' => '← Àtúnṣe tópẹ́jù',
+'nextdiff' => 'Àtúnṣe tótuntunjù →',

+# Media information
+'file-info-size' => '($1 × $2 pixel, ìtóbi faili: $3, irú MIME: $4)',
+'file-nohires' => 'Kò sí ìgbéhàn gíga jù báun lọ.',
+'svg-long-desc' => '(faili SVG, pẹ̀lú $1 × $2 pixels, ìtòbi faili: $3)',
+'show-big-image' => 'Pẹ̀lú ìgbéhàn gíga',
+'show-big-image-thumb' => 'Ìtóbi àyẹ̀wò yìí: $1 × $2 pixels',

+# Special:NewImages
+'newimages' => 'Ọ̀dẹ̀dẹ̀ àwòrán àwọn faili tuntun',

# Metadata
-'metadata' => 'Metadata',
+'metadata' => 'Metadata',
+'metadata-expand' => 'Àfihàn ẹ̀kúnrẹ́rẹ́',
+'metadata-collapse' => 'Ìbòmọ́lẹ̀ ẹ̀kúnrẹ́rẹ́',

+# External editor support
+'edit-externally-help' => 'Ẹ wo [http://www.mediawiki.org/wiki/Manual:External_editors ìlànà ìṣètò] fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.',
# 'all' in various places, this might be different for inflected languages
'watchlistall2' => 'gbogbo',
@@ -645,6 +906,14 @@ Bákannà ẹ tún ṣèlérí fún wa wípé ẹ̀yin lẹkọ́ fúnra arayín
'confirmemail_loggedin' => 'Ojúọ̀nà e-mail yín ti dájú.',
'confirmemail_subject' => 'Ìmúdájú ojúọ̀nà e-mail fún {{SITENAME}}',
+# Watchlist editing tools
+'watchlisttools-view' => 'Ẹ wo àwon àtúnṣe tóbaamu',
+'watchlisttools-edit' => 'Ìwò àti àtúnṣe ìmójútó',
+'watchlisttools-raw' => "Ẹ ṣ'àtúnṣe àkójọ ìmójútó látìbẹ̀rẹ̀",

+# Special:Version
+'version' => 'Àtúnṣe', # Not used as normal message but as header for the special page itself

# Special:SpecialPages
'specialpages' => 'Àwọn ojúewé pàtàkì',
'specialpages-group-maintenance' => 'Àwọn ìjábọ̀ ìtọ́jú',